Lara George – Ijoba Orun Lyrics

Ijoba Orun Lyrics By Lara George

Ijoba Orun Lyrics
Ijoba Orun Lyrics
  • Artist Lara George
  • Title Ijoba Orun
  • Album Forever In My Heart

Ijọba ọrun, l'ere onigbagbọ o
Ijọba ọrun, l'ere onigbagbọ o
Ma jẹ n ku'na, baba
Mu mi de'le o
Ma jẹ n ku'na, baba sẹ
Mu mi de'le o
Owo ti mo ni
Ko le mu mi de'le o
Mọto ti mo ri ra
Ko le wa mi de'le o
Ọrẹ ti mo ni
Ko le sin mi de'le o
Gbogbo iwe, ti mo ri ka
Wọn o le gbe mi re'le o
Ma jẹ n ku'na, baba
Mu mi de'le o
Ki n ma ku s'ajo
Bii eefin
Mu mi de'le o
Aye l'ọja
Ọrun n'ile
Mu mi de'le o
Aye l'ọja
Ọrun n'ile sẹ
Mu mi de'le o
Mu mi de'le o
Mu mi de'le o
Mu mi de'le o
Mu mi de'le o
Mu mi de'le o
Mu mi de'le o
Mu mi de'le o
Mu mi de'le o
Ma ma jẹ n ku'na
Baba o
Baba o
Mu mi de'le o
Mu mi de'le o
Mu mi de'le o
Mu mi de'le o
Mu mi de'le o
Ile ogo
Ile ayọ
Ile ayọ
Ile alaafia
Ile ogo
Ile ayọ
Ile ayọ, ile alayọ
Ijọba ọrun, l'ere onigbagbọ o
Ijọba ọba ọrun, l'ere onigbagbọ o
Ma jẹ n ku'na

READ ALSO  Lara George – Nobody Greater Lyrics

Leave A Comment