Asake – 2:30 (Mixed) Lyrics

2:30 (Mixed) Lyrics By Asake

2:30 (Mixed) Lyrics
2:30 (Mixed) Lyrics
  • Artist Asake
  • Title 2:30 (Mixed)
  • Album Africa Now: September 2023 (DJ Mix)

Awa de, awa de de
Awa lọmọ to n sọ ti o seke, ye
Orimọlade gbemi debẹ
Jigan Jigan, ẹsẹ mi o delẹ, delẹ
Alaye mi stop ṣe bẹẹ
O fẹ jẹ nbi, o tun fẹ jẹ n bẹ
O pọ sẹ
Agbawo, fẹnu fo fence
Sun sẹyin
A mọ ra wa, ṣo get?
Abinibi yatọ s'ability
Ẹ sọ fun wọn t'ọn ba tẹri si
Wọn maa palori
Tẹnu kọ, emi promising
Awọn tẹ fọ fun, fọ fun mi
Tori ko s'ẹlomi
Many, many fẹ dabi mi, ẹ ri bi
Ẹ gb'Ọlọrun tobi mo da aṣọ-ẹbi for my country
You can call me Mr Money
Hmm, hmm, hmm, hmm
2:30 fẹ lu
O ya ka turn up ki ilẹ to mọ
Hmm, hmm, hmm, hmm
2:30 fẹ lu ('30 fẹ lu)
O ya ka turn up ki ilẹ to mọ
Ere mo ba wa ko si ija
Ṣokoto penpe, ye
Aye nika, yebo, yeba
Formation lo gba, ye ja
Ọmọ'yami ko stay wise
Tranquility, tranquility
I no get time to dey form activity
Ko le kalas, I dey find stability
Like Abacha, money long infinity
What's the chances?
What's the probability?
To see a better version of me with agility
No you can't fake reality
Ogun, principality and calamity
Mo ti lọ, mo ti pa iyẹn ti
Bẹbẹ no dey for Jiji
O ṣi wa n titi
Still get money like Fifty
Dripping like Fiji
I be real gee
Hmm, hmm, hmm, hmm
2:30 fẹ lu
O ya ka turn up ki ilẹ to mọ
Hmm, hmm, hmm, hmm
2:30 fẹ lu
O ya ka turn up ki ilẹ to mọ

READ ALSO  Sarkodie – Round 2 (feat. Giggs) Lyrics

Leave A Comment