Kawasaki Lyrics By CDQ

Ọlọhun sẹ
Woss
Filẹ
Kowo wọle left right and the centre kowo wọle
T'ọn ba sọ pe awọn lo lẹnu jẹ k'ọn sọ pe
Ibi ti mo ba de ṣebi Oluwa lo de mi lade
Emi ni ma jaye mi
Wọn ni gbọku mi emi laye mi
All my ladies was up was up
All my lovers make una bless up, bless up
Una go see next stop
Una go see next stop
Ko lọ far
Holla baby was up was up
Ki lo fẹ sọ baby jẹ n mọ mọ mọ
O ya baby yẹn lọ gan-an gan-an gan-an
O ya baby yẹn lọ gan-an gan-an gan-an
Bayii bayii bayii, Alhaja she call me Alhaji
I like it ka ma kawasaki
Bounce bi ti Jabulani
Bayii bayii bayii, Alhaja she call me Alhaji
I like it ka ma kawasaki
Bounce bi ti Jabulani
Ko lọ far rara bẹ sinu mansory
J'a lọ kingfisher ka lọ mu ata sori
Make I buy u Prada show u dat I'm Prada u
Spend all d money in my acct I ain't mad at ya
Even to ba ṣẹ mo ma jẹbi
Sorry ass **** no go sorry for u
I go protect u by any means, ẹni to ba gas- jade pẹlu pump action
I gat money like soko
Now im getting money two times soko soko
No more bọ si kọrọ, now I bounce in d hood gbangba with ur ṣoko
Ntoor ki lẹ fẹ ṣe fún mi?
I'm too blessed Oluwa lo ṣe fún mi
Constantly owo yẹn wọle fún mi
Mi o gbọ pa leni ọmọ ọlọmọ lo n wun mi
Bayii bayii bayii, Alhaja she call me Alhaji
I like it ka ma kawasaki
Bounce bi ti Jabulani
Bayii bayii bayii, Alhaja she call me Alhaji
I like it ka ma kawasaki
Bounce bi ti Jabulani