Haystixx, L.A.X & Musiliu Haruna Ishola – Obirin Lyrics

Obirin Lyrics By Haystixx

Obirin Lyrics
Obirin Lyrics
  • Artist Haystixx
  • Featured L.A.X, Musiliu Haruna Ishola
  • Title Obirin
  • Album Obirin – Single

B'obìnrin ba niwa tútù bo tun rẹwa (Mo le fi ten million fẹ)
Mo le fi one thousand fẹ
B'obìnrin ba niwa tútù bo tun rẹwà
B'obìnrin ba niwa tútù bo tun rẹwà
B'obìnrin ba niwa to tun lọyan, nidi
Mo le fi one thousand fẹ
B'obìnrin ba lẹwa to tun lọyan, nidi
Mo lè fi one thousand fẹ
Tell me you love me, tell me you want me
Tell me something, something
Can't get enough of your love, girl you know, ain't lying and I'm not capping
Drunk in love I'm in the ocean, baby girl I'm drowning
To ba gbá kobo kan abọ mi o le fẹ
Ta lo lọmọ?
Ẹ ba mi gbé ìyàwó mi o, ta lo l'ọmọ o?
Emi o ṣọmọ
Emi ọṣọmọ
Ori ada ni taya o, emi o gbọmọ olọmọ o
All I need is one girl oh-oh
We gat one life, uh-uh
One night oh, oh
Jẹ ka ṣere de Morocco, de Morocco o, oh ah
B'obìnrin ba niwa to tun lọyan, nidi
Mo le fi one thousand fẹ
B'obìnrin ba lẹwa to tun lọyan, nidi
Mo lè fi one thousand fẹ
Ìyàwó mi, ma jẹ́ a ja o
Ìyàwó mi, ma jẹ́ a ja o
Ti a ba ja tan, ta lo ma lawa lẹjọ?
Ìyàwó mi, ma jẹ́ a ja o
Ki n mu nẹ, ṣom bọ si?
Ki n mu yọko, ṣem pa ẹ?
Ìyàwó mi, ma jẹ a ja o
B'obìnrin ba niwa to tun lọyan, nidi
Mo le fi one thousand fẹ
B'obìnrin ba lẹwa to tun lọyan, nidi
Mo lè fi one thousand fẹ
Lè fi one thousand fẹ
One thou', lè fi one thousand fẹ
To ba gbá kobo kan abọ mi o le fẹ

READ ALSO  L.A.X – Specially Lyrics

Leave A Comment