Naira Marley – Idi Oremi (Opotoyi, Pt. 2) Lyrics

Idi Oremi (Opotoyi, Pt. 2) Lyrics By Naira Marley

Idi Oremi (Opotoyi, Pt. 2) Lyrics
Idi Oremi (Opotoyi, Pt. 2) Lyrics
  • Artist Naira Marley
  • Title Idi Oremi (Opotoyi, Pt. 2)
  • Album Idi Oremi (Opotoyi, Pt. 2) – Single

Aye le aye akamara
Won fe so mi da ki n ṣe da
Ani opelope camera
A ba ma mo pe eyin naa wa
Mo ni e dakun e ma so bee mo
Pe ore o ki n jese ore
Ore maa n je ise ore
Ore maa n gbose ore
Je ka ma rira wa
Je ka ma gbora wa
Je ka ma shara wa
Je ka ma fora wa
Ṣe oko lo dun to yen
O ma ti pe mi pa
Ki la n pera wa lore fun
Ti n ba le muyen e pa
Idi ore mi ni emi o fi si
Idi ore mi o po to yi
Idi ore mi o fe to yi
Idi ore mi o po to yi
O ro boya mo ti ku
O ro boya mo ti sun
O wa fe fundi mi
O wa fe wodi mi
O fe ma taka mi
So le ba mi taka ni
Ti n ba ju banga mi
Igboro maa n gbadun mi
O fe maa yiwo
O fe maa daworu
O da pe o ti n d'oko n'ta
Set awon Okonta
O fe ma lamba mi
Ṣe mo jo Zlatan ni
O fe ma flatter mi
O fe dogbon mu Fanta mi
O fun mi loyan ko n ṣe mother mi
O pe mi zaddy ko n ṣe daughter mi
Pade mi ni Gaza mi
Ma gbagbe ganja mi
Tunde Fashola ni brother mi
Won ni f'elomi ṣe mother mi
Mo ti mu oyan mummy mi
Mo ti ri oyan mummy mi
Mo ni pe e mo meme
Te ba mo meme e mo mememe
Te ba mo mememe e mo memememe
Te ba mo memememe e mo Memememememe
Idi ore mi ni emi o fi si
Idi ore mi o po to yi
Idi ore mi o fe to yi
Idi ore mi o po to yi
Idi ore mi ni emi o fi si jo
Idi ore mi o po to yi
Idi ore mi o fe to yi
Idi ore mi o po to yi
To ba sure fun e bo gbangban
Shebi o lo modi gbon daadaa
O ṣe ore mi oni idi nla
Ṣe emi ati e le ma jo tungba
Ṣe idi e re abi o wo pampers
Mad! your ass they give me asthma, ah
Mo ni ko send number, ah
Why did you send aza?
Ṣe idi e re abi o da ogbon si
Je n fa na, je n foko si
Mo ṣe 1 hour o ni o fe si
Igba ta ṣe tan o pe mi ni bestie
Ha, what kind of bestie is that?
Mo fun bestie pussy massage
Beru Olohun, taqulah
E soko fun Ashaytan
Bi mo ṣe lo'rita
O da pe o tin je semovita
O da pe ori e fe ko j'iya
O da pe iwo omo yi ti n ni liver
Anyways
Idi ore mi ni emi o fi si
Idi ore mi o po to yi
Idi ore mi o fe to yi
Idi ore mi o po to yi
Idi ore mi ni emi o fi si jo
Idi ore mi o po to yi
Idi ore mi o fe to yi
Idi ore mi o po to yi

READ ALSO  Mercy Chinwo – Amaram Onyewem (feat. Pastor Jerry Eze) [Live] Lyrics

Leave A Comment