Intro Lyrics By Tml Vibez

Wọn wa mi gan-an ni
Ani wọn n wa mi
From Ipaja mo ti wa Americana
Any currency I go wire, ah
Tml o ki n waja ah ah
Ọmọ ọlọmọ, ọmọ ọlọmọ, Shanko bọbọ
Ọmọ t'ọn sọ, ọmọ t'ọn sọ pa wọn bọbọ
(Wọn wa mi)
America wọn n wa mi (Wọn n wa mi)
Wọn n wa mi gan-an (Wọn n wa mi)
Cyprus wọn n wa mi (Wọn n wa mi)
Ọmọ pupa wọn n wa mi (Wọn n wa mi)
Ọmọ dudu n wa mi (Wọn n wa mi)
(Wọn n wa mi)
(Wọn n wa mi)
Everything wey we do now money dey involve emi ọmọ ọgbọn
Dem tryna pull me down lai lai ko jọ ko sọmọ naa
24/7 eyes on the bag emi ọmọ Ọlọrun
Money shak pass alcohol