Gelato Lyrics By Cuppy

To copy this tune, press this
Kapaichumarimarichupako
Aiyii!
I go take you to Italy
I go take you to America
Take you to London
I go bring you come Nigeria
Just to have some gelato (Gelato)
My baby gelato (Gelato)
Ah! Sweet like gelato (Gelato)
O baby gelato (Gelato)
Ahhh Aiiyiii!
My people (Yeske)
How una dey? (We dey okay)
Everyday la fi n jaye bi ẹni gba Holiday (Ibilẹ)
My people (Yeske)
How una dey? (We dey okay)
Everyday la fi n jaye bi ẹni gba Holiday
Cuppy, who is your daddy (Otedola)
Baba temi, Babalola
Wo, ah, ẹ ma lọ wa
Ẹni to ba wa, o ma jẹya
Who is your daddy? (Otedola)
Baba temi, Babalola
Wo, ah, ẹ ma lọ wa
Ẹni to ba wa, o ma jẹya
Ọmọge gelato (Ah gelato) Gelato
Ọmọ to pọn, to dun bi gelato (Ah gelato)
Jẹ ki n gbẹnu si gelato (Ah gelato)
Wo, mo le gbe ẹ fo nitori gelato
Ṣo ma mu gelato? (Gbẹnu si jọ)
Ẹ gbọnsẹ fun ijalọ (Ẹ gbọnsẹ fun ijalọ)
O baby jẹ a lọ (O baby, let's go)
O baby let's go, o pọ
O to ko dẹngẹpo wo sẹ
Ọlọmọge gelato
Ayii, I gbadun your parol
Eh eh, wọn ni billionaire ni popsy ẹ, sunmọ mi jọ ka ma ro
Cuppy, who is your daddy (Otedola)
Baba temi, Babalola
Wo, ah, ẹ ma lọ wa
Ẹni to ba wa, o ma jẹya
Who is your daddy? (Otedola)
Baba temi, Babalola
Wo, ah, ẹ ma lọ wa
Ẹni to ba wa, o ma jẹya
Ọmọge gelato (Ah gelato) Gelato
Ọmọ to pọn, to dun bi gelato (Ah gelato)
Jẹ ki n gbẹnu si gelato (Ah gelato)
Wo, mo le gbe ẹ fo nitori gelato
Ṣo ma mu gelato? (Gbẹnu si jọ)
I go take you to Italy
I go take you to America
Take you to London
I go bring you come Nigeria
Just to have some gelato (Gelato)
My baby gelato (Gelato)
Ah! Sweet like gelato (Gelato)
O baby gelato (Gelato)
To ba jẹ ti jijẹ, m'o ni jẹ ajẹju
Bọ 'bi ọmọ akẹju (Ọmọ akẹju) Eh
Ibilẹ Zlatan
Fun wọn jẹ loni plenty pattern
To ba jẹ ti jijẹ, m'o ni jẹ ajẹju
Ibilẹ, I'm on a new level
Ah ah new pattern
Ah, give them lamba
Eh eh