Reminisce – Recycle Lyrics

Recycle Lyrics By Reminisce

Recycle Lyrics
Recycle Lyrics
  • Artist Reminisce
  • Title Recycle
  • Album ATSG, Vol. 1

Lyrics Alaga o ṣe recycle
Mo ni congregation to n study iṣẹ yẹn bi bible
Decade old lyric, but shit's still the same though
Multiple **** fucking the same hoe
Ain't nothing changed since I dropped the last one, eh?
Rap **** dancing, guilty as charged, eh
Lamba limbo, afrobeats, rap, reggae
Anyone to ba gbe wa, man, I'll show you ṣege
Alaga on seke, Ọja no be ofege
I'm your favorite rapper's favorite rapper, ask am, eh-eh?
Piece of warning fun awọn ọmọ alaigbọran
A ma ṣa a yin ni baṣi , awa eeyan menọmọ
Mo ti lo lyric yẹn ria, but ẹ ma jẹ k'ọn mọ
Ibilẹ Army ẹ ṣe o, ẹ ku oju lọna
Ṣe o ti pe 16 abi ki n ṣi maa lamba lọ?
Ki n ma tu si wọn ni furọ k'ọn maa tamba lọ
Awa n fa ganja lọ, wọ ṣokoto wa ba ijalọ
Awọn tẹ jọ n ṣoriburuku ni kẹ ma ba ja lọ
Not to be spoken to, not to be fucked with
Not to be tweeted about, ewo ni fuck shit?
O ti pe bẹyẹn, o ti rẹ mi

READ ALSO  Olamide – Hustle Loyalty Respect Lyrics (feat. Reminisce)

Leave A Comment