Alabi [Remix] Lyrics By Damzee Abaamin
![Alabi [Remix] Lyrics by Damzee Abaamin Alabi [Remix] Lyrics](https://rynx.com.ng/wp-content/uploads/2026/10/alabi-remix-lyrics-by-damzee-abaamin-Cover-rhyto-25248-rynx.com_.ng_.png)
Alabi gbowo (O gbowo)
Alabi fowo mọti mọti o ṣa claro
Alabi like biggy bumbum o gbe Caro
Ta lo m'Alabi, ta lo m'Alabi?
Alabi gbowo (O gbowo)
Alabi fowo mọti mọti o ṣa claro
Alabi like biggy bumbum o gbe Caro
Ta lo m'Alabi, ta lo m'Alabi?
Ṣe you know the time?
Ṣe you know the day?
T'ọn maa ki emi naa pe oriire mi de
Chinchín 1 million yẹn ko le kariile
Ẹ wo ibi tẹ ba mi de
Alabi kan lorile
Inu jogodo gan-an lati fa local o
Aṣabi ti n gba dollar o
P popo o rọ popo mọ o ti wa bọla o
Ọmọ jẹ ka gbowo lọ ọmọ jẹ ka tẹṣẹ
Alabi lo loko gan-an ko n ṣe fọmọ to gbẹ sẹ
Spending all money ye ye wọn ni mo ta bi ata ṣawa
Alabi o gbọ nnkan kan, yeh o ti fowo lọ gba daya
Everyday we celebrate no money no power
Emi kan n jaye mi lọ I get power
Alabi gbowo (O gbowo)
Alabi fowo mọti mọti o ṣa claro
Alabi like biggy bumbum o gbe Caro
Ta lo m'Alabi, ta lo m'Alabi?
Alabi gbowo
Alabi fowo mọti mọti gbelepawo
Alabi like biggy bumbum o gbe Caro
Ta lo m'Alabi, ta lo m'Alabi?
Ta lo m'Alabi?
I see many chaos for my party o
We dey puff backwood pumping pari o
Abike ti jonz she say daddy o
She no mind benson ti ko sariwo
Alabi gba wire
Alabi ṣe picker
Kile ma daworo Alabi ṣe dealer
Alabi gbowo
Alabi fowo mọti mọti o ṣa claro
Alabi like biggy bumbum o gbe Caro
Ta lo m'Alabi, ta lo m'Alabi?
Alabi gbowo (O gbowo)
Alabi fowo mọti mọti o gbe Caro
Ta lo m'Alabi, ta lo m'Alabi?