All Eyes On Me Lyrics By Portable

Oh oh oh, ọba bi Ọlọrun kosi oh
Wowowo, oh oh oh, ọba bi Ọlọrun kosi oh, oh oh ah
Ologo l'ọn ma n ya ni photo, ologo l'ọn ma n fowope oh
Ologo l'ọn ma fowowo oh
Iwo naa sunmo ologo awe to ba fe logo
Let me hear you sing pass Wande Coal oh, awe ṣo ti blow
Ọmọ Ọlọrun, SOJ
Apata ni mi, mi o se kọlu
Ọmọ eniyan lawọn to n ro lẹsẹ to n fọloju
Maluu ti ko n'iru, Ọlọrun lo n ba leṣin danu
Ki lo wa ṣe mi ti mi o ni dupẹ oh
Aakakatan oh, niṣẹ rẹ laye mi, oh oh oh
Ko sẹni naa to le nifẹmi bo ṣe nifẹmi
Ilahi Ọlọrun la mi o, ka bi ọ o si oh, ọba to n fọba jẹ
Oṣubare rẹ oh, mo juba ọba to daye
Ọba to dọrun ṣa ma ṣọla rẹ lọ
Tant'Ọlọrun, tant'Ọlọrun, tant'Ọlọrun laye
Laye lọrun kosi oh, kosi oh oh
Tant'Ọlọrun, tant'Ọlọrun, tant'Ọlọrun laye n bi o
Laye lọrun kosi oh, ah, ahn
I can see all eyes on me
Gbogbo oju to n wo mi
Gbogbo eti to n gbọ mi oh
Ni ko ma fi rie wa mi ri oh oh oh
I can see all eyes on me
Brother pray for me oh, sister pray for me
Thanks to those people whey dey show me love oh
Oju o ma ni ti yin
I gat this believe in Ọlọrun n bẹ lẹyin mi oh oh oh
Oluwa ma jẹ k'ọn ri mi tan oh
Ma jẹ kọmọ araye ri mi danwo
Ma ṣe mi lologo ọjọ kan
Ologo ọsẹ kan, ologo osun kan
Ma ṣe mi lologo ọdun kan oh
Ọba ilahi ṣe mi lologo forever oh
Ti mo ba ji lowurọ, ma gbadura oh
K'ori mi gbe mi leke ọta oh
Amọniṣeni, abanidaro oh
Awọn arogo siwaju ologo
Ti mo ba ji lowurọ ma gbadura oh
Ki n ri batiṣe, ki n rọna gbe gba oh
Ogo pọnmọ yatọ sogo tinko oh
Emayilo ogo Oluwa ni oh
I do music for living
Orin ni mo fi n gawuu
Ogo pọnmọ yato sogo tinko
Emayilo o pukutuah, pukutuah mehn mehn mehn
Aloyinlohun re, emi ni were olorin
Idamu adugbo, ọmọ Ọlalọmi again oh
Dem call me Portable baby oh
Son of Shakushaku oh
Mo ti kọrin pẹlu Barry, mo ti kọrin pẹlu Barry star
Mi o le kusẹ mọ oh
I’m now a superstar, I’m a big man
Are you mad or something? Zehh ko to zehh ori e