Dupe Lyrics By Pasuma

Titi on the beat
Baba da mi lohun o
Jọwọ gbe mi leke o
Tori lọsan loru o
Iwọ ni mo n ke pe o
Ibi ori mi a ti sanre o
Ẹsẹ gbe mi de'bẹ o
To ba d'oni gbegbegbe
Baba ma jẹ n le'lẹ o, amin
Maa dupẹ
To ba kọle fun mi, kọle fun mi o
Maa dupẹ
To ba ra mọto fun mi, ra mọto fun mi
Maa dupẹ
To ba fun mi lowo, ba fun mi lowo
Maa dupẹ o
Ọlọrun maa dupẹ
When I was young
I have ambition
To become a person
For better living
Pasuma wonder wọn da mọ
Ọmọ ologo wọn ti mọ
Every corner n'ọn ti n gbọ
Ngbọgbọ na ngbọgbọ
Pasuma wonder wọn da mọ, wọn da mọ
Ọmọ ologo wọn ti mọ, wọn ti mọ
Every corner n'ọn ti n gbọ, ti n gbọ
Ngbọgbọ na ngbọgbọ
Maa dupẹ
To ba kọle fun mi, kọle fun mi o
Maa dupẹ
To ba ra mọto fun mi, ra mọto fun mi
Maa dupẹ
To ba fun mi lowo, ba fun mi lowo
Maa dupẹ o
Ọlọrun maa dupẹ
Baba da mi lohun o
Jọwọ gbe mi leke o, gbe mi leke o
Tori lọsan loru o
Iwọ ni mo n ke pe, ni mo n ke pe o
Ibi ori mi a ti sanre o
Ẹsẹ gbe mi de'bẹ o, ẹsẹ gbe mi de'bẹ o
To ba d'oni gbegbegbe
Baba ma jẹ n le'lẹ, amin
Maa dupẹ
To ba kọle fun mi, kọle fun mi o
Maa dupẹ
To ba ra mọto fun mi, ra mọto fun mi
Maa dupẹ
To ba fun mi lowo, ba fun mi lowo
Maa dupẹ o
Ọlọrun maa dupẹ
Maa dupẹ
To ba kọle fun mi
Iba Wasilatu o
Maa dupẹ
To ba ra mọto fun mi
Opeyemi l'America
Maa dupẹ
To ba fun mi lowo
Ọmọ iyawo anabi, Aliyah ni Chicago
Maa dupẹ o
Ọlọrun maa dupẹ o
Daddy Baraka o
Titi on the mix