Sean Tizzle – Eruku Sa’Ye Po Lyrics

Eruku Sa'Ye Po Lyrics By Sean Tizzle

Eruku Sa'Ye Po Lyrics
Eruku Sa'Ye Po Lyrics
  • Artist Sean Tizzle
  • Title Eruku Sa'Ye Po
  • Album Eruku Sa'Ye Po

Mo ti hustle l'Orile
Mo ti gbe l'Ajegunle oh
Baba ba mi ṣe temi fun mi
O ya, o ya ba mi dupẹ oh
Ikorodu ṣa nile wa
Awọn temi l'Ebute Metta
Gọngọ a sọ kutupu a wu
Gọngọ ti sọ
Ọdun n lọ sopin oh Baba Mimọ
Fiṣọ rẹ ṣọ mi oh, tọmọ tọmọ
Ohun to pa mi lẹkun lọdun tuntun
Ma jẹ ko ṣẹlẹ si mi Baba
Ẹruku ṣaye pọ
Ẹruku ṣaye pọ
O ya ẹ wa jẹ ka flẹnjọ
Jẹ ka flẹnjọ
Jẹ ka flẹnjọ ni
Everyday for the hustle
One day for the hustler
Bi mo ṣe n tẹpamọṣẹ
Baba mo tun n gbadura
Aye mi odi ọwọ rẹ Baba
Ọwọ rẹ eh, eh
Baba ma doju ti mi laye
Ibi tawọn ẹgbẹ mi ti n fi nawo
Baba ma jẹ nara
Baba jẹ ki n nawo
Ooh
Ọdun n lọ sopin oh Baba Mimọ
Fiṣọ rẹ ṣọ mi oh, tọmọ tọmọ
Ohun to pa mi lẹkun lọdun tuntun
Ma jẹ ko ṣẹlẹ si mi Baba
Ẹruku ṣaye pọ
Ẹruku ṣaye pọ
Ẹruku ṣaye pọ
Ṣaye pọ
Ṣaye pọ
Ẹruku ṣaye pọ
Tizzle ko le ye wọn
Blacky black blacky dove oh
Lo ṣe beat
Ṣebi, ṣebi black lo ṣe beat
Ṣebi Tizzle lo kọrin
Black lo ṣe beat
Awọn eleyii lakọrin
Ṣebi Tizzle, awọn meji lo kọrin
Yeah yeah
Will be dancing dancing dancing all the way
Ikorodu ṣa nile wa
Awọn temi l'Ebute Metta
Gọngọ a sọ kutupu a wu
Ibi t'ọn ti pejọ t'ọn sọrọ mi laida
Ẹruku ṣaye gan-an ni
Tizzle ko le ye wọn
Ẹruku ṣaye
Tizzle ko le ye
Tell me ko le ye
Ori mi ba mi ṣe oh

READ ALSO  Shaarib & Toshi, Jyotica Tangri & Kumaar – Ishq De Fanniyar - Female Lyrics

Leave A Comment