Gbe Gbe Lyrics By 9ice

Ibi tẹ ni ki gbegbe ma gbe
Ibẹ lo n gbe, ibẹ lo n gbe
O dara si'bẹ ibẹ lo n gbe
Ibi tẹ ni ki tẹtẹ ma tẹ, o tẹ ẹ pẹpẹ
Pẹpẹ, ah, d'ọjọ alẹ
Orin wa super o ta sansan
Ilu orin wa sugar o dun mọran-in
Ọgbọn orin wa super ko lafiwe
Adun wa super o lọ fẹfẹ
You say baba no dey do normal
Baba no dey do proper
But still baba ni father lọjọkọjọ
O ki fun mi ma a ki fun ẹ
O jẹju mi ma a jẹju ẹ
Ẹyẹ mi o dede ba lorule, ọrọ lẹyẹ n gbọ
Emi ni amu wọn ti ko gbẹ
Wọn pọn ọn lojoojumọ ko ma gbẹ
Emi ni amu wọn ti ko gbẹ
Wọn pọn ọn but still living in self deny
Ibi tẹ ni ki gbegbe ma gbe
Ibẹ lo n gbe, ibẹ lo n gbe
O dara si'bẹ ibẹ lo n gbe
Ibi tẹ ni ki tẹtẹ ma tẹ, o tẹ ẹ pẹpẹ
Pẹpẹ, ah, d'ọjọ alẹ
Orin wa super o ta sansan
Ilu orin wa sugar o dun mọran-in
Ọgbọn orin wa super ko lafiwe
Adun wa sugar o lọ fẹfẹ
K'ọn ye ṣagidi
K'ọn ye ṣagidi
K'ọn ye ṣagidi
K'ọn ye ṣagidi
K'ọn lọ gbafẹfẹ
K'ọn lọ gbafẹfẹ
Ọdọ wa lorin wa o
K'ọn ye ṣagidi
K'ọn ye ṣagidi
K'ọn ye ṣagidi
K'ọn lọ gbafẹfẹ
K'ọn lọ gbafẹfẹ
K'ọn lọ gbafẹfẹ
Ọdọ wa lorin wa o
Ko ma gbẹ
It's Bizzle on the mix
Ti ko gbẹ