Intro Lyrics By 9ice

O fẹ morukọ mi?
Segun mo n jẹ
Wọn ma n pe mi ni Lord of Ajasa
Lord of Flavor, Lord hush
Jẹ o mọ
Ah check it out
Ọjọ re bi ana
Mo gbe bed sori mo gba Bariga lọ
Akure lati n bọ
Accident pọ lọna Oluwa lo ko mi yọ
A ma debẹ dandan baba determination
Mo ti ji mo ti jọgọ
Ọmọ o pọ
A dẹ fọ fẹni kankan
Cause a mọra wa gan-an
Baba baddest recovery
Total new something
9ice ṣo ranti?
Rice iya Ngozi
Orin ta fi n kọ nigba yẹn
Wọn ṣi n jo si
Eko ile, ilu aje
Gbogbo ibi la wa ṣaye de
One bag pere ni mo gbe wọle
A fi ra motor a dialaye
Dream come true awa lo n jẹ bẹẹ
Ma sọ pe mi o sọ fun ẹ tẹlẹ
Nigba ti a n fọwọ lu table labẹtẹ
Tawọn ọmọ oṣi maa n fi wa ṣe yẹyẹ
Bad vibe, kia ni mo move away
Make them no dey use their negative energy spoil my day
Mi o kuku fọ, oju wọn lo ṣe
Iṣẹ ta ṣe silẹ wọn ṣi n kowo le
Jẹ ko mọ, jẹ ko mọ, jẹ ko mọ