Ireti Lyrics By Oritse Femi

Oritse Femi ni oh
YAGI level
Oh ye ye ye yea
Mo gbori mi soke (Gbori mi soke) s'Olodumare (S'Olodumare)
Tori ewu n bẹ lode mo mọ
As I dey hustle everyday (Hustle everyday)
To get my bread eh (To get my bread eh)
Fi iṣọ rẹ ṣo mi lọ oh
With you ah, ireti n bẹ (Ireti n bẹ oh)
Alafia n bẹ oh, ireti n bẹ (Ireti n bẹ)
Alafia n bẹ oh ireti n bẹ (Ireti n bẹ)
Alafia n bẹ oh (Ireti n bẹ)
Alafia n bẹ oh
All the problems I don face for my life that that one dey make me stronger, eh ba
Ta ba b'ewu lọna ti ko ba pani, o yẹ ko gbeniga ni oh, oh oh ye ye
Mi ko waye wa jiya, eh ba, mo waye wa jọrọ ni oh
Emi o waye wa ṣeka oh, mo wa ran awọn ọmọ araye lọwọ ni oh
Ọpọ lo n sunkun nile oh, k'ọn to bode wọn fe fẹyin jade
Stop looking at another man life because your life is big and better
Ye ye ye ye ih, dakun gbawa Oluwa oh, o ya nao
Oh eh eh eh, eh woh, iwọ ṣa ni agbẹkẹle wa
Mo gbori mi soke (Gbori mi soke) s'Olodumare (S'Olodumare)
Tori ewu n bẹ lode mo mọ
As I dey hustle everyday (Hustle everyday)
To get my bread eh (To get my bread eh)
Fi iṣọ rẹ ṣo mi lọ oh
With you ah, ireti n bẹ (Ireti n bẹ oh)
Alafia n bẹ oh, ireti n bẹ (Ireti n bẹ)
Alafia n bẹ oh ireti n bẹ (Ireti n bẹ)
Alafia n bẹ oh (Ireti n bẹ)
Alafia n bẹ oh
Skibo, ọmọ ologo ti gbera
Enemies, see you later yea yea
Cos am making paper (Paper)
Them no like me but my God is greater (Skibo)
Alubarika lo ju (Lo ju)
E go fall on me and fall on you (On you)
Where you dey when I call on you?
Ball on me, I ball on you
Ah, I don't sleep, always grinding bi ẹni n lọta
Make God bless my bread with butter
Ṣọ mi lọ, ṣọ mi bọ, k'ọta mi ma get mi
Jẹ k'ẹmi wọn gun k'ọn le ri mi ninu jet mi
Celebrate
Jubilate
Mo gbori mi soke (Gbori mi soke) s'Olodumare (S'Olodumare)
Tori ewu n bẹ lode mo mọ
As I dey hustle everyday (Hustle everyday)
To get my bread eh (To get my bread eh)
Fi iṣọ rẹ ṣo mi lọ oh
With you ah, ireti n bẹ (Ireti n bẹ oh)
Alafia n bẹ oh, ireti n bẹ (Ireti n bẹ)
Alafia n bẹ oh ireti n bẹ (Ireti n bẹ)
Alafia n bẹ oh (Ireti n bẹ)
Alafia n bẹ oh
I say, 30 Billion no be for mouth
O ma ṣiṣẹ owo gidi ko tun le gbẹnu si
This one no be for mouth
The more you focus, the much more you win, eh
Make we stop to dey talk many things, ye
My brother, make we work towards it
I know say everybody like to get it
Alabi gbori ọmọ s'apo, nitori owo ni oh
Ih ye, ih ye
Ohun t'owo ma fa, aya o ni ka oh, ih ye, ih ye
Ile-aye yi le gan-an oh, ih yeh eh, ih ye
Gbogbo ohun t'owo ma fa, aya o le ka wọn oh, ih ye
Ohun t'owo ma fa, aya mi n ja gan-an oh, ih ye
Ohun t'owo ma fa, aya mi n gan-an oh, oh oh
Oh ye ye oh