Oil and Gas Lyrics By Olamide

Igbe, igbe, igbe-gbe-gbe, igbe
Egbe, egbe-gbe-gbe, egbe
Ọga mi ẹnu gbẹ
Ọ̀rẹ́ mi, ẹnu gbẹ
Alaye, ẹnu gbẹ
Walahi ẹnu gbẹ
Owó wa lọwọ́ yín
Ẹ jẹ ká ba yín ná
Epo wa lọwọ́ yín
Ẹ jẹ ká ba yín lá
Ẹ le náwó yẹn tàn
Ẹ le l'epo yẹn tàn
Ẹ le náwó yẹn tàn
Ẹ le l'epo yẹn tàn, eh
Owó wa lọwọ́ yín
Ẹ jẹ ká ba yín ná
Epo wa lọwọ́ yín
Ẹ jẹ ká ba yín lá
Tony elumelu
Wá ba mi jó sílú
Femi Otedola
È̩ ná mí ní dollar
Asiwaju Jagaban
Ghana must go bag
Oba Elegushi
È̩ ná mí n kukushi
Asiwaju tí bínú
Wọn ni mi o mọ law
Wọn ni kín ye gbé Ghana must go wá s'ilé àwọn ni Bourdillon
Ọmọ, ọmọ bullion van, yei
L'ọn fí gbé wá fún mi, eh
Dapo Abiodun
O yí bíríbírí kàn mi
Ọga mi ẹnu gbẹ
Ọ̀rẹ́ mi, ẹnu gbẹ
Alaye, ẹnu gbẹ
Walahi ẹnu gbẹ
Owó wa lọwọ́ yín
Ẹ jẹ ká ba yín ná
Epo wa lọwọ́ yín
Ẹ jẹ ká ba yín lá
Ẹ le náwó yẹn tàn
Ẹ le l'epo yẹn tàn
Ẹ le náwó yẹn tàn
Ẹ le l'epo yẹn tàn, eh
Owó wa lọwọ́ yín
Ẹ jẹ ká ba yín ná
Epo wa lọwọ́ yín
Ẹ jẹ ká ba yín lá
Èyàn Shina Peller
My honourable
MC Musiliu
È̩yín lẹnu dákú
IBD Dende
Áfúnnimàwobẹ
Seyi Tinubu
Ògo Lagos, oun lojú Eko
O mọ̀ Kunle Poly
O mọ̀ 1805
O mọ̀ Igbalode
Gucci, Gucci, èyàn Hushpuppi
Àwa lá ni Lagos
(Na we get this Lagos)
Ẹyín lẹ n'ìlé yín
(Ẹyín lẹ ni Lekki)
O mọ̀ Dangote
Cementi wọn lọ fí kọ ilé yín
Ọmọ ase!
Ọga mi ẹnu gbẹ
Ọ̀rẹ́ mi, ẹnu gbẹ
Alaye, ẹnu gbẹ
Walahi ẹnu gbẹ
Owó wa lọwọ́ yín
Ẹ jẹ ká ba yín ná
Epo wa lọwọ́ yín
Ẹ jẹ ká ba yín lá
Ẹ le náwó yẹn tàn
Ẹ le l'epo yẹn tàn
Ẹ le náwó yẹn tàn
Ẹ le l'epo yẹn tàn, eh
Owó wa lọwọ́ yín
Ẹ jẹ ká ba yín ná
Epo wa lọwọ́ yín
Ẹ jẹ ká ba yín lá
Maintain bi t'Olu
Ko ye jó Yahooze
To o ba Sanwo Olu
Wa ṣa sanwó toll gate, yei
Riddimakolayo
Maintain bi t'Olu
Ko ye jó Yahooze
To o ba Sanwo Olu
Wa ṣa sanwó toll gate, yei