SPINALL – Omoge (feat. Dotman) Lyrics

Omoge Lyrics By SPINALL

Omoge Lyrics
Omoge Lyrics
  • Artist SPINALL
  • Featured Dotman
  • Title Omoge
  • Album Iyanu

Right about now
Ladies, fellas
Dotman
Ori lo ba mi ṣe
Wa wo bowo ṣe n wọle
Mo ma lowo lọmọde, ma dẹ tun ni lagba o
Ọmọ ọlọpẹ tun wọle
Ẹ jẹ k'ọn ṣọti wọle
Ma ṣaye f'ọmọde, ma dẹ tun ṣe f'agba o (Oh yeh)
Sunmọ mi Monalisa ọmọge
Aye la-vida-loca lo ma jẹ
Emi dẹ ti n na dollar f'ọmọge (Ọmọge)
A ṣọmọ DJ Spinall lọmọ yẹn
Sunmọ mi Monalisa ọmọge
Aye la-vida-loca lo ma jẹ (Lo ma jẹ)
Emi dẹ ti n na dollar f'ọmọge, f'ọmọge (Ye)
A ṣọmọ DJ Spinall lọmọ yẹn
Sexy lady no dey dull no dey dull on me
To o ba le jo, ko ṣa ma redi o, redi o yeah
Pretty lady ba mi jo jẹ ki n nawo sanwo
To o ba le jo, ko ṣa ma redi o, redi o yeah
Hmm yewe, hmm ye
Hmm yewe, hmm ye
Hmm yewe, hmm ye
Hmm yewe, hmm ye
Hmm yewe, hmm ye
Hmm yewe, hmm ye
Hmm yewe, hmm ye
Hmm yewe, hmm ye
Ori lo ba mi ṣe
Wa wo bowo ṣe n wọle
Mo ma lowo lọmọde, ma dẹ tun ni lagba o
Ọmọ ọlọpẹ tun wọle
Ẹ jẹ k'ọn ṣọti wọle
Ma ṣaye f'ọmọde, ma dẹ tun ṣe f'agba o (Oh yeh)
Sunmọ mi Monalisa ọmọge
Aye la-vida-loca lo ma jẹ (Lo ma jẹ)
Emi dẹ ti n na dollar f'ọmọge
A ṣọmọ DJ Spinall lọmọ yẹn (Ẹ gba mi o)
Sunmọ mi Monalisa ọmọge (Ọmọge)
Aye la-vida-loca lo ma jẹ, lo ma jẹ
Emi dẹ ti n na dollar f'ọmọge, f'ọmọge
A ṣọmọ DJ Spinall lọmọ yẹn (Ẹ gba mi o)
Ọmuti gbagbe iṣẹ, o dakeregbe bori
Ọmuti gbagbe iṣẹ, o dakeregbe bori
Ọmuti gbagbe iṣẹ, o dakeregbe bori
Ọmuti gbagbe iṣẹ, o dakeregbe bori
Hmm yewe, hmm ye
Hmm yewe, hmm ye
Hmm yewe, hmm ye
Hmm yewe, hmm ye
Hmm yewe, hmm ye
Hmm yewe, hmm ye
Hmm yewe, hmm ye
Hmm yewe, dakeregbe bori
Hmm yewe, hmm ye
Hmm yewe, hmm ye
Hmm yewe, hmm ye
Hmm yewe, hmm ye
Hmm yewe, hmm ye
Hmm yewe, hmm ye
Hmm yewe, hmm ye
Hmm yewe
Thank you for coming out tonight
They call me DJ Spinall
Get home safe, drive safe
Don't drink and drive
Don't talk to no strangers

READ ALSO  SPINALL – Oshey (feat. BNXN fka Buju & Stefflon Don) Lyrics

Leave A Comment