Oritse Femi & Portable – Oro Aje Lyrics

Oro Aje Lyrics By Oritse Femi

Oro Aje Lyrics
Oro Aje Lyrics
  • Artist Oritse Femi
  • Featured Portable
  • Title Oro Aje
  • Album IDAN

Awọn kan ma lowo, awọn kan o ni le lowo
Ohun a ni la a nani
Owo tẹni tele no o
Pokotua ma-ma-ma o
Aje mi ni, owo mi ni ko kan yin (Ko kan aye)
Bi mo ṣe n pawo mi ṣebi emi mo mọ mi (Jaypizzle production)
Tẹ ba le sọrọ aje
Tori ọrọ aje
Ọrọ aje yẹn lo sure ju
Ika o buru eeyan lo n gbero ika
Ẹda aye le, ori ẹni lo n gbeniga
Iya o yẹ mi, ayọ lo yẹniyan
K'emi ṣa ma pawo mi ki n ma jaye deede
T'emi ni kowo ti pe ki n dẹ wa'bi to gbayi lọ
Ma jaye ori ma tun ṣoore f'awọn eeyan kan
Awọn kan ma gbẹnusi, k'ọn le ba ti wọn ma lọ
Ahh, mo ti pawo mi mo ma ṣaye deede
Baba mo rọwọ rẹ ninu aye mi
Aye mi dara o mo wa ṣọpẹ
Ẹlẹda mi gbe mi depo ade mi
Ori aje mi ma ṣe jẹ ko bọ o
Aah, ṣebi ọla mi, aje mi ni ko kan yin
Wọn ṣe bọla tan o
Ọla kun sẹyin o pọ gan-an
Tẹ ba le sọrọ aje
Tori ọrọ aje
Ọrọ aje yẹn lo sure ju
Ika o buru eeyan lo n gbero ika
Ẹda aye le, ori ẹni lo n gbeniga
Iya o yẹ mi, ayọ lo yẹniyan
K'emi ṣa ma pawo mi ki n ma jaye deede
T'emi ni kowo ti pe ki n dẹ wa'bi to gbayi lọ
Ma jaye ori ma tun ṣoore f'awọn eeyan kan
Awọn kan ma gbẹnusi, k'ọn le ba ti wọn ma lọ
Ahh, mo ti pawo mi mo ma ṣaye deede
Alonyinlohun re o
Tori k'ọn ma lọ ri mi tan nii mo ṣe sapamọ o
Ma pe mi ki n wa lọ ja o, owo ni o pe mi ki n wa lọ gba o
Ọmọ oro mi wuwa ika o
Ọmọ oro mi sapamọ o
K'ọn ma lọ ri ẹ tan o
Is better than see finish o, ṣo le ṣe tiẹ bẹẹ?
Ko kọle ko ma yọ window
Oritse Femi gbe mi trabaye
Zazoo ze o
Emi ni were olorin
Idamu adugbo yin
Wahala musician
Africa mafian
Awoooo
Hmm, awọn ọmọ Naija
Awọn l'ọn ma ṣe yahoo
Tori ko sowo ni
Ika o buru eeyan lo n gbero ika
Ẹda aye le, ori ẹni lo n gbeniga
Iya o yẹ mi, ayọ lo yẹniyan
K'emi ṣa ma pawo mi ki n ma jaye deede
T'emi ni kowo ti pe ki n dẹ wa'bi to gbayi lọ
Ma jaye ori ma tun ṣoore f'awọn eeyan kan
Awọn kan ma gbẹnusi, k'ọn le ba ti wọn ma lọ
Ahh, mo ti pawo mi mo ma ṣaye deede
Ma pe mi ki n wa lọ ja o, owo ni ko pe mi ki n wa lọ gba o
Ma jẹ k'ọn rip ẹ
K'ọn to rip ẹ o aburo mi salọ
Pa data o biza biza o
Zeh k'ọn to zeh ori ẹ
Musical Taliban number 1
Acha MSN Gang ye
Swapsi

READ ALSO  Oritse Femi – Ene Dede Lyrics

Leave A Comment