Sean Tizzle – Perfect Gentle Man Lyrics

Perfect Gentle Man Lyrics By Sean Tizzle

Perfect Gentle Man Lyrics
Perfect Gentle Man Lyrics
  • Artist Sean Tizzle
  • Title Perfect Gentle Man
  • Album Eruku Sa'Ye Po

Sean Tizzle, oh
Ọrọ ifẹ ṣa lo n ṣe mi
D Tunez again oh
Ọrọ ifẹ ṣa lo n ṣe mi eh
Ọrọ ifẹ ṣa lo n ṣe mi
Ifẹ ṣa lo n ṣe mi
Let me be your, a perfect gentleman oh
Let me be the man to always hold you down
Could you be the one for me
Obimo
Nwanyi oma (Yeba)
Ọmọ daadaa lọmọ yẹn o (Yeba)
Ọmọ gidi lo mu wale o
Oh no, ọmọ daadaa lọmọ yẹn o
Hmm, ọmọ gidi lo mu wale o
A ma kọlemọle oo (Amin o)
A ma bimọlemọ (Amin o)
A o ni sunkun ọkọ (Amin o)
A o ni sunkun aya (Amin o)
A ma kọlemọle oo (Amin o)
A ma bimọlemọ (Amin o)
A o ni sunkun ọkọ (Amin o)
A o ni sunkun aya
Let me be your man 'til the end of time
Let me take you by the hand, walk you down aisle
Let me kiss your lips before we sleep for night
Ooh baby, come with me a thousand miles
(Baby o) ifẹ wa ko ni bomi lọ
(Baby, yeah) ko dẹ ni bomi lọ
She likes me, I like her too
She call me baby, I call her boo
And there is no losing you
Let me be your, a perfect gentleman oh
Let me be the man to always hold you down
Could you be the one for me
Obimo
Nwanyi oma
Ọmọ daadaa lọmọ yẹn o (Yeba)
Ọmọ gidi lo mu wale o
Oh no, ọmọ daadaa lọmọ yẹn o
Hmm, ọmọ gidi lo mu wale o
A ma kọlemọle oo (Amin o)
A ma bimọlemọ (Amin o)
A o ni sunkun ọkọ (Amin o)
A o ni sunkun aya (Amin o)
A ma kọlemọle oo (Amin o)
A ma bimọlemọ (Amin o)
A o ni sunkun ọkọ (Amin o)
A o ni sunkun aya
Komọle, komọle
Komọle, komọle
Ohun naa niyẹn
Ifẹ ṣa lo n ṣe mi
Let me be your, a perfect gentleman oh
Let me be the man to always hold you down
Could you be the one for me
Obimo
Nwanyi oma
Ọmọ daadaa lọmọ yẹn o (Yeba)
Ọmọ gidi lo mu wale o
Oh no, ọmọ daadaa lọmọ yẹn o
Hmm, ọmọ gidi lo mu wale o
A ma kọlemọle oo (Amin o)
A ma bimọlemọ (Amin o)
A o ni sunkun ọkọ (Amin o)
A o ni sunkun aya (Amin o)
A ma kọlemọle oo (Amin o)
A ma bimọlemọ (Amin o)
A o ni sunkun ọkọ (Amin o)
A o ni sunkun aya
Amin o
Amin o
Amin o
Amin o
Amin o
Amin o
Amin o

READ ALSO  Lil Wayne – I Do It (feat. Big Sean & Lil Baby) Lyrics

Leave A Comment