Ramadan Lyrics By Tolibian

Saari, saari ti to Muslim ẹ dide n'lẹ kẹ jẹun o
Ehn, lọsan Ramadan
Oju mi ti ri lọsan Ramadan
B'ọn gbounjẹ wa mi o ni le jẹ o
B'ọn gbomi wa mi o ni le mu o
Agba to lomi 'nu o ki n pariwo mo ti n gbawẹ
Ramadan Ramadan
Oluwa jẹ ki n ranu gba o
Oṣu oriire Baba jẹ ki n rire gba o
Ka fayọ bẹrẹ ka tun pejọ tunu awẹ
Ka ma ṣe fibanujẹ gba pupọ to n bọ
All my wishes unto thy Lord
What's the time? The sun is setting
Ẹjọ wẹwẹ dakun ẹ ma gbe wa ba mi ẹ jọọ
Ẹ ma ṣe pe mi tẹ ba pejọ lati ṣabosi o
Awẹ ti de o Ramadan
I for like go Medina
Emi o le san fine igbo
Ma ya fasalatu ranṣẹ
Lọsan Ramadan
Ohun oju mi ri lọsan Ramadan (Lọsan Ramadan)
Awuyewuye lọsan Ramadan (Lọsan Ramadan)
Iru ki leleyi lọsan
Soli Allah Muhammadu
Ẹyin ọmọ oro
Allahumma salli Allah Muhamadu
Ẹyin ọmọ oro
Ya rosululah ya Muhammadu
Allahumma salli Allah Muhamadu
Saari, saari ti to Muslim ẹ dide n'lẹ kẹ jẹun o
Ehn, lọsan Ramadan
Oju mi ti ri lọsan Ramadan
B'ọn gbounjẹ wa mi o ni le jẹ
B'ọn gbomi wa mi o ni le mu o
Agba to lomi 'nu o ki n pariwo mo ti n gbawẹ
Ẹ ye fa bakki lọsan Ramadan
Ẹ ye gboloṣo lọsan Ramadan
Ẹ ma ṣe ṣaṣẹ ninu Ramadan
O ṣi tun wẹṣẹ ninu Ramadan