Sha Guide Lyrics By Portable

Tuti on the beat
Ọmọ Ọlalọmi again o, they call me Portable baby (Popo when)
Ija wa ija o si (Ṣa guide)
Da ti ẹ mọ (Ṣa guide)
Eeyan wa eeyan o si (Ṣa guide)
E get why (Ṣa guide)
Sabo plus Oluwore (Ṣa guide)
Wọn a ṣẹke sinu idi ẹ (Ṣa guide)
Wọn a fẹnu gba pata n'di ẹ (Ṣa guide)
Elo lo wa l'account ẹ? (Ṣa guide)
Ha, ogun laye (Ṣa guide)
Logun awure, ṣogun ayẹta (Ṣa guide)
If you price you go pay (Ṣa guide)
Olowo l'ọn pe lalaye (Ṣa guide)
Ọmọ dudu, ọmọ pupa
Gbogbo wọn ni mo ti pa
Elo ni price ẹ?
Mo ma fi universe gba pata n'di ẹ
Mo ma fún ẹ ni lion
To gbe money gun dani (Ṣa guide)
Mufasa mufasa (Ṣa guide)
Lion ẹkun mẹfa (Ṣa guide)
Talo fa ẹ laṣọ ya?
Sunmọ ẹni ti iwọ ba ja
Ọgbẹni gbori ẹ sa nibi t'ọn ti n yin ṣakabula
Ija wa ija o si (Ṣa guide)
Da ti ẹ mọ (Ṣa guide)
Eeyan wa eeyan o si (Ṣa guide)
E get why (Ṣa guide)
Sabo plus Oluwore (Ṣa guide)
Wọn a ṣẹke sinu idi ẹ (Ṣa guide)
Wọn a fẹnu gba pata n'di ẹ (Ṣa guide)
Elo lo wa l'account ẹ? (Ṣa guide)
Ha, ogun laye (Ṣa guide)
Logun awure, ṣogun ayẹta (Ṣa guide)
If you price you go pay (Ṣa guide)
Olowo l'ọn pe lalaye (Ṣa guide)
Ọmọ ki lo fi ṣe ibadi? O ya ligali
Ṣe Southy lo ti ṣebadi?
Nobody is calling me
O ya liga ligali mo tun ti de
Ohun to ba wu wọn ni k'ọn sọ
Liga ligali awa tun ti de o
T'owo ba de gọngọ a sọ
Money gun mẹfa fun eeyan kan
Baby lion mẹta fun ẹnikan
Ẹ fun lọrun pa
Ẹ yi loruka
Ija wa ija o si (Ṣa guide)
Da ti ẹ mọ (Ṣa guide)
Eeyan wa eeyan o si (Ṣa guide)
E get why (Ṣa guide)
Sabo plus Oluwore (Ṣa guide)
Wọn a ṣẹke sinu idi ẹ (Ṣa guide)
Wọn a fẹnu gba pata n'di ẹ (Ṣa guide)
Elo lo wa l'account ẹ? (Ṣa guide)
Ha, ogun laye (Ṣa guide)
Logun awure, ṣogun ayẹta (Ṣa guide)
If you price you go pay (Ṣa guide)
Olowo l'ọn pe lalaye (Ṣa guide)
Tuti on the mix