UPDATE Lyrics By SuperWozzy

O di dandan dandan
All my gee Pablo o di dandan dandan
We gon carry big bumbum bumbum
Nigboro ko lẹnu bi pon pon pon pon
Mo lẹruku, mo lẹruku
Me I been blow codeine tryna lose my cool
Gbowo ko daju pa, ko dẹ sanju pa
Hungry man is an angry man
Agba wire to n sọkẹ si mi
Awọn ọmọ Yahoo kan n oppress mi
Iṣẹ wo lo n lọ na kẹ ja mi?
Iṣẹ wo lo n lọ na kẹ ja mi?
Mo lẹgbọn adugbo to n sọkẹ si mi
Awọn ọmọ Yahoo kan n oppress mi
Iṣẹ wo lo n lọ na kẹ ja mi?
Iṣẹ wo lo n lọ na kẹ ja mi?
The devil is the liar, liar
Davidi ni mi awọn ọta mi ni Goliath
Ọmọ akin o ki n ṣojo ẹ dẹ mo pe mo laya
Mi o dẹ dawa
Ẹruku yapa bi seven million ninu barrack
Emi ni ija bo ogiri o sa
Ninu jungle, ẹ dẹ mọ pe Lion ni mi bi Mufasa
K'ọn ma foribalẹ fun mi bi ooṣa
Wọn n jẹ ni Lekki, wọn tun damọ ni Mushin Olosha
Agba wire dẹ ti sọkẹ, tonight we gon ball like Okocha
Holy Micheal wa loda
Ọrun nile aye lọja, wọn ni ki n ye jọja
Wọn ni k in jẹ k'ori mi pe, ọmọ mi ma lọ loose-guard o
Ọba imọlẹ! Jesu, K'Ọlọrun fọrun kẹ Mohbad o
Agba wire to n sọkẹ si mi
Awọn ọmọ Yahoo kan n oppress mi
Iṣẹ wo lo n lọ na kẹ ja mi?
Iṣẹ wo lo n lọ na kẹ ja mi?
Mo lẹgbọn adugbo to n sọkẹ si mi
Awọn ọmọ Yahoo kan n oppress mi
Iṣẹ wo lo n lọ na kẹ ja mi?
Iṣẹ wo lo n lọ na kẹ ja mi?
Iṣẹ wo lo n lọ na kẹ ja mi?
Ọmọ ẹru le d'ọba, mo le pada wa gba Grammy
Iṣẹ wo lo n lọ na kẹ ja mi?
Ko sere ni Moscow, iṣẹ ni wọn n ṣe ni Germany
Na why I carry my cross, cos I gat no one to carry am
Fell in love with my hustle, then I marry am
Everything on God, I put my trust in the Most High
Bread winner of the family, hin mama dey pray make he no die
Agba wire to n sọkẹ si mi
Awọn ọmọ Yahoo kan n oppress mi
Iṣẹ wo lo n lọ na kẹ ja mi?
Iṣẹ wo lo n lọ na kẹ ja mi?
Mo lẹgbọn adugbo to n sọkẹ si mi
Awọn ọmọ Yahoo kan n oppress mi
Iṣẹ wo lo n lọ na kẹ ja mi?
Iṣẹ wo lo n lọ na kẹ ja mi?