Wayward Lyrics By 9ice

Ṣìkìṣìkì máa mì
Ó ń mì, ó ń mì
Ó ń mì, ó ń mì
Ṣìkìṣìkì máa mì
If you think say I be wayward say I no go fit dey pop bottle
Ma mu páṣapàṣa kítikìti sí’bibí
Are you feeling like I do that no one been dey respect you
Wayward
I know I do my thing like no one
Whoa whoa whoa whoa whoa
Wayward
I know I do my thing like no one
Whoa whoa whoa whoa whoa
Ṣìkìṣìkì máa mì
Ṣìkì ṣìkìṣìkì máa mì owó dé
Ṣìkìṣìkì má a mì
Ṣìkìṣìkì ṣìkìṣìkì má a mì Owó de
Ṣìkìṣìkì máa mì
Ṣìkì ṣìkìṣìkì máa mì
Ṣìkì ṣìkìṣìkì má a mì owó dé
Ṣìkìṣìkì má a mì
Dem say I’m just a baller
Wey no need bouncer dédé
Regular spender
Àpà tí ò mọ ohun tí wọ́n ń fowó ṣe
Wọ́n ní bó pẹ́ ńta gan-an
Àti kó èrè oko délé pé kòní ṣe é ṣe
Ah, ojú wọn lá ṣe
When you see me cruising up and down (Jiggy jiggy)
Lamboginni dey all around
Who dey dare? Who dey counter? (Jiggy jiggy)
Who dey price? Who dey count down?
Can you see what it’s all about
Told you now can't be cool to be fool
Ah, jiggy now
Talk about physical, physical
It's all about the cheddar, more cheddar
Ẹní lówó tí ò bá le na kó lọ jókòó
Ẹni lówó tí ò bá le na kó lọ jókòó
Ẹni lówó tí ò bá m'ará kó lọ jókòó
Ẹni lówó tí ò bá m'ẹbí kó lọ jókòó
Ah, pọ́nrán mi ti ń lago (Lago lago)
Tí pọ́nrán mi ti ń lago (Lago lago)
Wayward
I know I do my thing like no one
Whoa whoa whoa whoa whoa
Wayward
I know I do my thing like no one
Whoa whoa whoa whoa whoa
Ṣìkìṣìkì máa mì
Ṣìkì ṣìkìṣìkì máa mì owó dé
Ṣìkìṣìkì máa mì
Ṣìkìṣìkì ṣìkìṣìkì má a mì owó de
Ṣìkìṣìkì máa mì
Ṣìkì ṣìkìṣìkì máa mì
Ṣìkì ṣìkìṣìkì máa mì owó dé
Ṣìkìṣìkì má a mì
(Má a mì mì mì)
(Má a mì mì mì)
Èmi èmi ọmọ Anífowóṣe
Èmi èmi ọmọ Anífowóṣe
Èmi èmi ọmọ Anífowóṣe
Èmi èmi ọmọ Anífowóṣe