9ice – Bounce (feat. Lord of Ajasa) Lyrics

Bounce Lyrics By 9ice

Bounce Lyrics
Bounce Lyrics
  • Artist 9ice
  • Featured Lord of Ajasa
  • Title Bounce
  • Album Lord of Ajasa

Jẹ ko bounce daadaa ko bounce daadaa
Ma wọ bra daadaa ko bounce daadaa
Jẹ ko bounce daadaa ko bounce daadaa
Wa gba pounds daadaa ko bounce daadaa
Jẹ ko bounce daadaa ko bounce daadaa
Ma wọ bra daadaa ko bounce daadaa
To ba bounce daadaa
Wa gba dollars daadaa
Jẹ ko bounce daadaa
Ko ṣe normal daadaa
Ọmọ ọba n gbeṣẹ yẹn o ṣa mọ bo ṣe n lọ
Gbe mi debẹ ma jẹ n wa lasan
Jumping jumping who is in the garden
Nawọ ẹ soke to o ba like igbadun
Emi ọpẹ tipẹtipẹ
No dey settle for less
Bẹyẹn lo ṣe maa jẹ
Aye yẹn a maa jẹ
Cause a ti faṣẹ
And a tun gbọpẹ, gba bẹẹ
Ẹ fọbẹ si, ẹ fọbẹ si
Ki lo de gan-an ṣe ẹ n ṣahun ọbẹ ni?
Mo ma ti gbagbe oṣi mi o use mọ tanṣo mọ
Kaka bẹẹ apaṣẹ o ni ṣagbo mọ
Put all the ace in backwood
Ko ma lọ bẹẹ zazuu
Shoutout sawọn temi Eko lagoon
At'awọn ọmọ yẹn ti wọn fi gbogbo idi ṣe tattoo
Jẹ ko bounce daadaa ko bounce daadaa
Ma wọ bra daadaa ko bounce daadaa
Jẹ ko bounce daadaa ko bounce daadaa
Wa gba pounds daadaa ko bounce daadaa
Jẹ ko bounce daadaa ko bounce daadaa
Ma wọ bra daadaa ko bounce daadaa
To ba bounce daadaa
Wa gba dollars daadaa
Jẹ ko bounce daadaa
Ko ṣe normal daadaa
Ọmọ mehn o skiribobo
Mamacito jẹ n lalapino
Jẹ a collabo fọke sobo
Mama solo rọra lo dildo
Ọmọ yẹ mi wo emi ọmọ iko
Beere mi ni gboro you won't let me go
On a down low koko below
On a down low koko be-low
Be far to me fine girl don't fear
Come close to me
Took a long time before you talk to me
Now is the right time let get naughty
Fun fun fun time is fun fun fun
You see your bumbum want to make man dey jigbọngbọn jigbọngbọn
Jẹ ko bounce daadaa ko bounce daadaa
Ma wọ bra daadaa ko bounce daadaa
Jẹ ko bounce daadaa ko bounce daadaa
Wa gba pounds daadaa ko bounce daadaa
Jẹ ko bounce daadaa ko bounce daadaa
Ma wọ bra daadaa ko bounce daadaa
To ba bounce daadaa
Wa gba dollars daadaa
Jẹ ko bounce daadaa
Ko ṣe normal daadaa
Fun fun fun fun fun emi fun
Fun fun fun fun is being a long time
I say fun fun fun fun is being a long time
Fun fun fun fun fun emi fun
Set to me, gbadun mi
Ṣe daadaa ko dẹ gbadun mi
Ṣe daadaa ko gbadun mi
Holla to me come close to me
Its Bizzle mix
O pọ o pọ
Who dey check am?

READ ALSO  Black Sherif – Oh Paradise Lyrics

Leave A Comment