Ere Lyrics By 9ice

Owo mo wa pa mi o ba toṣi wa o
Ere mo wa ṣe mi o ba tija wa o
Enemy dey beside me ṣungbọ mi o ri wọn
Wọn pariwo nita ṣungbọ mi o gbọ wọn
Gbogbo aroye wọn ko ma ye mi
A o wa ṣere o (A o wa ṣere)
A o wa ṣere o (A o wa ṣere)
Ọmọ ta gbe wa ko kekere o
Ija lẹ ba wa a o wa ṣere o
Mo ti pẹ n'ta tipẹ o (Pẹ n'ta gan-an)
Mo ti pẹ n'ta tipẹ o (Pẹ n'ta gan-an)
Mo ṣe ere ọmọ de ti pe o (Pẹ n'ta gan-an)
Mo ti daye tipẹ o
Ẹ wa wa ooh ooh
Ẹ wa wa ooh ooh
Ẹ wa wa ooh ooh
Ere mo wa ṣe mi o ba tija wa o
Owo mo wa pa mi o ba toṣi wa o
Music in my vein mi o ba tija wa o
Music I dey play mi o ba toṣi wa o
Ẹ wa wa ooh ooh
Ẹ wa wa ooh ooh
Ehh Ehh ooh ooh
Enemy I go over them
Enemy I go over them
Enemy I go over them
Enemy I go over them
Enemy I go over them
Wọn petepero over them
Petepero see I'm over them
Wọn lọ ile babalawo kan
Emi gan-an babalawo kan nibi kan
O lọ ile oniṣegun kan
Emi gan-an wọn gbe iwe fun mi nibi kan
Ah, emi ọmọ Agibola ọmọ Ẹdan
Ohun ta ba fọn fun fere yẹn ṣa lo maa fọn
Gbọ na
This season o maa yatọ
Faaji nisẹyi o kọ sisọ
See many many things la ti ṣe ri
O ra Hennessy kan o wa fẹ ma ba mi gbegba
I'm over them tipẹ tipẹ ni
Mo ma ti mọ itọwo ibẹ tipẹ tipẹ gan-an
Me I ran all over them tipẹ tipẹ
Me I just dey gboju n'bẹ emi ọmọ ọpẹ
I'm over them
Enemies I'm over them
Apetepero over them still
Adigun over them babalawo
Gbese re oh
Gbese re fun awọn ọta mi
Gbese re oh
Gbese re fun awọn ẹni ibi
Gbese re oh
Gbese re fun awọn ọta mi
Gbese re oh
Gbese re fun awọn ẹni ibi
You are over them Adigun
You be on them Adigun
You above them Adigun o
O ju wọn lọ Adigun tipẹ tipẹ
Aro Kese tipẹ tipẹ
Aro Kese tipẹ tipẹ
Ọwọnrin-ṣe-ogbe tipẹ tipẹ