Olorun Lyrics By Asake

Ololade mi Asake
Emi kọ, Ọlọrun ma ni
Emi kọ o, Ọlọrun ma ni
Awa kọ, ọ ọ
Emi kọ, Ọlọrun ma ni
Ta lo gbọn t’Ọlọrun?
Ko si anybody to lọgbọn t’Ọlọrun
Ti wọn ba buga ẹ o ya gba f’Ọlọrun
Awọn ti wọn buga mi wọn ti sapamọ
Wọn ti sapamọ
Emi kọ o, Ọlọrun ma ni
Emi kọ o, Ọlọrun ma ni
Awa kọ, Ọlọrun ma ni o
Emi kọ o, Ọlọrun ma ni o
Ọmọ no be me ṣebi na God
Carry me from down, straight to the top
2020, it was real tough
Fall for ground, almost gave up
Mo fun wọn lọmọ-ọpẹ mo dẹ jẹ lọ
Go naked in my room and speak to God
Baba God I no sabi all
So guide me as I dey move on, on, on
Ta lo gbọn t’Ọlọrun?
Ko si anybody to lọgbọn t’Ọlọrun
Ti wọn ba buga ẹ o ya gba f’Ọlọrun
Awọn ti wọn buga mi wọn ti sapamọ
Wọn ti sapamọ
Emi kọ o, Ọlọrun ma ni
Emi kọ o, Ọlọrun ma ni
Awa kọ, Ọlọrun ma ni o
Emi kọ o, Ọlọrun ma ni o
Emi kọ o, Ọlọrun ma ni
Emi kọ o, Ọlọrun ma ni
Awa kọ, Ọlọrun ma ni o
Emi kọ o, Ọlọrun ma ni o
Nnkan o gbọdọ ṣọmọ ologo
Mimi kan o gbọdọ mi ọmọ Ọlọrun
Alhamdulillah, I’m a brand new man